ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìgbàgbọ́ Wa Ń Sún Wa Ṣe Àwọn Iṣẹ́ Rere
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba—2002 | May
    • 1 Ìgbàgbọ́ ló sún Nóà, Mósè àti Ráhábù ṣe àwọn ohun tí wọ́n ṣe. Nóà kan ọkọ̀ áàkì. Mósè kọ àwọn àǹfààní onígbà kúkúrú tí ì bá máa gbádùn nínú àgbàlá Fáráò sílẹ̀. Ráhábù fi àwọn amí pa mọ́, lẹ́yìn náà ó ṣègbọràn sí ìtọ́ni tí wọ́n fún un, ó sì tipa bẹ́ẹ̀ gba ìdílé rẹ̀ là. (Heb. 11:7, 24-26, 31) Àwọn iṣẹ́ rere wo ni ìgbàgbọ́ wa ń sún wa ṣe lónìí?

  • Ṣé Ò Ń Lo Ìwé Pẹlẹbẹ Béèrè Láti Bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba—2002 | May
    • 1 Ǹjẹ́ o mọ̀ pé tó o bá ń bá ẹnì kan jíròrò nípa Bíbélì déédéé, tí o sì ń lo ọ̀kan lára àwọn ìwé tá a dámọ̀ràn, kódà bí àkókò tí ò ń lò kò bá tiẹ̀ gùn, ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lò ń darí yẹn? Dájúdájú, bó ṣe rí nìyẹn, bó tiẹ̀ jẹ́ ẹnu ọ̀nà lẹ̀ ń dúró sí ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ náà tàbí lórí tẹlifóònù. O ò ṣe ṣe gbogbo ohun tó o bá lè ṣe ní oṣù May àti June láti bẹ̀rẹ̀ irú ìkẹ́kọ̀ọ́ bẹ́ẹ̀ nípa lílo ìwé pẹlẹbẹ Béèrè?

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́