ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 18-20
Tí Jèhófà Bá Ti Dárí Ẹ̀ṣẹ̀ Jini, Ṣé Ó Máa Ń Gbàgbé Rẹ̀?
- Bí Jèhófà bá ti dárí ẹ̀ṣẹ̀ ji ẹnì kan, kò ní fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ náà jẹ ẹ́ lọ́jọ́ iwájú. 
Àwọn àpẹẹrẹ inú Bíbélì yìí fi wá lọ́kàn balẹ̀ pé Jèhófà ń dárí jini.
Ọba Dáfídì
- Ẹ̀ṣẹ̀ wo ló dá? 
- Kí nìdí tí Jèhófà fi dárí jì í? 
- Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun ti dárí jì í? 
Ọba Mánásè
- Ẹ̀ṣẹ̀ wo ló dá? 
- Kí nìdí tí Jèhófà fi dárí jì í? 
- Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun ti dárí jì í? 
Àpọ́sítélì Pétérù
- Ẹ̀ṣẹ̀ wo ló dá? 
- Kí nìdí tí Jèhófà fi dárí jì í? 
- Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun ti dárí jì í?