APÁ 2 Bíi Ti Orí Ìwé Ohun tó dá lé: Ohun tí Ọlọ́run ti ṣe fún wa àti ọ̀nà tó fẹ́ ká máa gbà jọ́sìn òun Ẹ̀KỌ́ 13 Ẹ̀sìn Èké Kò Ṣojú fún Ọlọ́run 14 Báwo La Ṣe Lè Mọ Ìjọsìn Tí Ọlọ́run Tẹ́wọ́ Gbà? 15 Ta Ni Jésù? 16 Kí Ni Jésù Ṣe Nígbà Tó Wà Láyé? 17 Irú Ẹni Wo Ni Jésù? 18 Bá A Ṣe Lè Mọ Àwọn Kristẹni Tòótọ́ 19 Ṣé Kristẹni Tòótọ́ Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà? 20 Bá A Ṣe Ṣètò Ìjọ Kristẹni 21 Báwo La Ṣe Ń Wàásù Ìhìn Rere? 22 Bó O Ṣe Lè Máa Wàásù Ìhìn Rere Fáwọn Èèyàn 23 Ìrìbọmi Ṣe Pàtàkì! 24 Ohun Tó Yẹ Ká Mọ̀ Nípa Àwọn Áńgẹ́lì 25 Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Dá Wa? 26 Kí Nìdí Tí Nǹkan Burúkú Fi Ń Ṣẹlẹ̀ Tá A sì Ń Jìyà? 27 Báwo Ni Ikú Jésù Ṣe Gbà Wá Là? 28 Fi Hàn Pé O Mọyì Ohun Tí Jèhófà àti Jésù Ṣe fún Ẹ 29 Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ Sáwọn Tó Ti Kú? 30 Àwọn Èèyàn Rẹ Tó Ti Kú Ṣì Máa Jíǹde! 31 Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? 32 Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso! 33 Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe fún Aráyé