ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • lfb ojú ìwé 106-107
  • Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 8

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 8
  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Sólómọ́nì Fọgbọ́n Ṣàkóso
    Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
  • Àkókò Yìí Gan-an Ló Yẹ Kó O Gbé Ìgbésẹ̀ Kánkán
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • Ṣé Àpẹẹrẹ Rere Ló Jẹ́ Fún ẹ Àbí Àpẹẹrẹ Búburú?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Ìwọ Yóò Ha Jẹ́ Olùṣòtítọ́ Bí Èlíjà Bí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1997
Àwọn Míì
Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
lfb ojú ìwé 106-107
Ọba Sólómọ́nì dá ìyá tó ni ọmọ mọ̀

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 8

Jèhófà bù kún Sólómọ́nì gan-an, ó fún un lọ́gbọ́n, ó sì jẹ́ kó kọ́ tẹ́ńpìlì fóun. Àmọ́ nígbà tó yá, Sólómọ́nì fi Jèhófà sílẹ̀. Tó o bá jẹ́ òbí, jẹ́ kọ́mọ ẹ mọ bí ìbọ̀rìṣà ṣe mú kí Sólómọ́nì fi Jèhófà sílẹ̀. Ìjọba Ísírẹ́lì pín sí méjì, àwọn ọba búburú tó jẹ sì mú káwọn èèyàn náà máa jọ́sìn òrìṣà. Lákòókò yẹn, ọ̀pọ̀ àwọn wòlíì Jèhófà ni wọ́n fìyà jẹ tí wọ́n sì pa. Jésíbẹ́lì tó jẹ́ ayaba tún mú káwọn èèyàn túbọ̀ máa jọ́sìn àwọn òrìṣà. Nǹkan burú gan-an fáwọn ọmọ Ísírẹ́lì lákòókò yìí. Síbẹ̀, ọ̀pọ̀ èèyàn jẹ́ olóòótọ́ sí Jèhófà. Lára wọn ni Ọba Jèhóṣáfátì àti wòlíì Èlíjà.

Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ

  • Máa sin Jèhófà tọkàntọkàn kódà táwọn ìdílé ẹ àtàwọn ọ̀rẹ́ ẹ ò bá sìn ín

  • Tó o bá fi Jèhófà sílẹ̀, nǹkan ò ní lọ dáadáa fún ẹ, àmọ́ tó o bá dúró ti Jèhófà, ó máa bù kún ẹ

  • Nígbà míì tó bá dà bíi pé ìṣòro wa ò lè yanjú, Jèhófà máa fi agbára ẹ̀ gbà wá lọ́nà tó máa yà wá lẹ́nu

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́