- 
	                        
            
            B12-A Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kìíní)Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        B12-A Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kìíní)Jerúsálẹ́mù àti Agbègbè Rẹ̀- Tẹ́ńpìlì 
- Ọgbà Gẹ́tísémánì (?) 
- Ààfin Gómìnà 
- Ilé Káyáfà (?) 
- Ààfin Tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà Lò (?) 
- Adágún Omi Bẹtisátà 
- Adágún Omi Sílóámù 
- Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn (?) 
- Gọ́gọ́tà (?) 
- Ákélídámà (?) 
 Lọ sí ọjọ́ tó o fẹ́: Nísàn 8 | Nísàn 9 | Nísàn 10 | Nísàn 11 Nísàn 8 (Sábáàtì)ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀, ó sì máa ń parí sí ìgbà tí oòrùn bá wọ̀)- Ó dé sí Bẹ́tánì lọ́jọ́ mẹ́fà ṣáájú ọjọ́ Ìrékọjá 
 ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀Nísàn 9ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀- Ó bá Símónì adẹ́tẹ̀ jẹun 
- Màríà da òróró náádì sí Jésù lórí 
- Àwọn Júù wá wo Jésù àti Lásárù 
 ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ- Ó wọ Jerúsálẹ́mù tiyì-tẹ̀yẹ 
- Ó kọ́ni ní tẹ́ńpìlì 
 ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀Nísàn 10ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀- Ó sun Bẹ́tánì mọ́jú 
 ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ- Ìrìn àjò ní kùtùkùtù sí Jerúsálẹ́mù 
- Ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́ 
- Jèhófà sọ̀rọ̀ látọ̀run 
 ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀Nísàn 11ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ- Ó kọ́ni ní tẹ́ńpìlì, ó lo àpèjúwe 
- Ó dẹ́bi fún àwọn Farisí 
- Ó kíyè sí ọrẹ tí opó kan ṣe 
- Lórí Òkè Ólífì, ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ ìparun Jerúsálẹ́mù àti àmì ìgbà tó máa wà níhìn-ín 
 ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            B12-B Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kejì)Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        B12-B Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kejì)Jerúsálẹ́mù àti Agbègbè Rẹ̀- Tẹ́ńpìlì 
- Ọgbà Gẹ́tísémánì (?) 
- Ààfin Gómìnà 
- Ilé Káyáfà (?) 
- Ààfin Tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà Lò (?) 
- Adágún Omi Bẹtisátà 
- Adágún Omi Sílóámù 
- Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn (?) 
- Gọ́gọ́tà (?) 
- Ákélídámà (?) 
 Lọ sí ọjọ́ tó o fẹ́: Nísàn 12 | Nísàn 13 | Nísàn 14 | Nísàn 15 | Nísàn 16 Nísàn 12ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀, ó sì máa ń parí sí ìgbà tí oòrùn bá wọ̀)ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ- Òun àtàwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jọ wà níbi tó pa rọ́rọ́ 
- Júdásì ṣètò bí wọ́n ṣe máa mú Jésù 
 ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀Nísàn 13ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ- Pétérù àti Jòhánù múra sílẹ̀ fún Ìrékọjá 
- Jésù àtàwọn àpọ́sítélì yòókù dé ní ọjọ́rọ̀ 
 ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀Nísàn 14ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀- Òun àtàwọn àpọ́sítélì rẹ̀ jẹ Ìrékọjá 
- Ó fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì 
- Ó ní kí Júdásì máa lọ 
- Ó dá Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa sílẹ̀ 
 Nísàn 15 (Sábáàtì)ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ- Pílátù gbà pé kí wọ́n fi àwọn ẹ̀ṣọ́ ṣọ́ sàréè Jésù 
 ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀Nísàn 16ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ- Ó jíǹde 
- Ó fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn 
 ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀
 
-