ÀÌSÁYÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Bàbá kan àti àwọn ọmọ rẹ̀ tó ya ọlọ̀tẹ̀ (1-9) 
- Jèhófà kórìíra ìjọsìn ojú lásán (10-17) 
- “Ẹ jẹ́ ká yanjú ọ̀rọ̀” (18-20) 
- Síónì máa pa dà di ìlú olóòótọ́ (21-31) 
 
-  2  
-  3  
-  4  
-  5  - 
- Orin nípa ọgbà àjàrà Jèhófà (1-7) 
- Ó mà ṣe fún ọgbà àjàrà Jèhófà o (8-24) 
- Ọlọ́run bínú sí àwọn èèyàn rẹ̀ (25-30) 
 
-  6  - 
- Ìran nípa Jèhófà nínú tẹ́ńpìlì rẹ̀ (1-4) 
- A wẹ ètè Àìsáyà mọ́ (5-7) 
- Àìsáyà gba iṣẹ́ (8-10) 
- “Títí dìgbà wo, Jèhófà?” (11-13) 
 
-  7  - 
- A ránṣẹ́ sí Ọba Áhásì (1-9) 
- Ohun tí a fi máa dá Ìmánúẹ́lì mọ̀ (10-17) 
- Ohun tó máa gbẹ̀yìn ìwà àìṣòótọ́ (18-25) 
 
-  8  - 
- Ásíríà máa gbé ogun wá (1-8) 
- Ẹ má bẹ̀rù—“Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa!” (9-17) 
- Àìsáyà àti àwọn ọmọ rẹ̀ máa jẹ́ àmì (18) 
- Ẹ yíjú sí òfin, kì í ṣe sí àwọn ẹ̀mí èṣù (19-22) 
 
-  9  
- 10  - 
- Ọwọ́ Ọlọ́run máa kọ lu Ísírẹ́lì (1-4) 
- Ásíríà—Ọ̀pá ìbínú Ọlọ́run (5-11) 
- Ìyà tó máa jẹ Ásíríà (12-19) 
- Àṣẹ́kù Jékọ́bù máa pa dà (20-27) 
- Ọlọ́run máa dá Ásíríà lẹ́jọ́ (28-34) 
 
- 11  
- 12  
- 13  
- 14  - 
- Ísírẹ́lì máa gbé ní ilẹ̀ tirẹ̀ (1, 2) 
- Wọ́n fi ọba Bábílónì ṣe ẹlẹ́yà (3-23) 
- Ọwọ́ Jèhófà máa fọ́ ará Ásíríà túútúú (24-27) 
- Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Filísíà (28-32) 
 
- 15  
- 16  
- 17  
- 18  
- 19  
- 20  
- 21  
- 22  
- 23  
- 24  
- 25  
- 26  
- 27  
- 28  - 
- Ó mà ṣe fún àwọn ọ̀mùtípara Éfúrémù o! (1-6) 
- Àwọn àlùfáà àti wòlíì Júdà ń ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́ (7-13) 
- Wọ́n “bá Ikú dá májẹ̀mú” (14-22) 
- Bí Jèhófà ṣe ń fi ọgbọ́n báni wí (23-29) 
 
- 29  
- 30  - 
- Íjíbítì ò lè ṣèrànwọ́ kankan (1-7) 
- Àwọn èèyàn ò fetí sí àsọtẹ́lẹ̀ (8-14) 
- Ìgbẹ́kẹ̀lé máa fi hàn pé wọ́n lágbára (15-17) 
- Jèhófà ṣojúure sí àwọn èèyàn rẹ̀ (18-26) 
- Jèhófà máa dá Ásíríà lẹ́jọ́ (27-33) 
 
- 31  
- 32  - 
- Ọba kan àti àwọn ìjòyè máa ṣàkóso fún ìdájọ́ òdodo (1-8) 
- A kìlọ̀ fún àwọn obìnrin tí ara tù (9-14) 
- Tí a bá tú ẹ̀mí jáde, ó máa mú ìbùkún wá (15-20) 
 
- 33  
- 34  
- 35  
- 36  
- 37  - 
- Hẹsikáyà ní kí Àìsáyà bá òun bẹ Ọlọ́run fún ìrànlọ́wọ́ (1-7) 
- Senakérúbù halẹ̀ mọ́ Jerúsálẹ́mù (8-13) 
- Àdúrà tí Hẹsikáyà gbà (14-20) 
- Àìsáyà sọ ohun tí Ọlọ́run sọ (21-35) 
- Áńgẹ́lì kan pa 185,000 àwọn ọmọ Ásíríà (36-38) 
 
- 38  
- 39  
- 40  
- 41  - 
- Aṣẹ́gun kan láti ìlà oòrùn (1-7) 
- Ọlọ́run yan Ísírẹ́lì pé kó jẹ́ ìránṣẹ́ òun (8-20) 
- Ó pe àwọn ọlọ́run míì níjà (21-29) 
 
- 42  - 
- Ìránṣẹ́ Ọlọ́run àti ohun tó máa ṣe (1-9) 
- Orin ìyìn tuntun sí Jèhófà (10-17) 
- Ísírẹ́lì fọ́jú, ó sì dití (18-25) 
 
- 43  - 
- Jèhófà pa dà kó àwọn èèyàn rẹ̀ jọ (1-7) 
- Kí àwọn ọlọ́run gbèjà ara wọn (8-13) 
- Wọ́n máa tú wọn sílẹ̀ láti Bábílónì (14-21) 
- “Jẹ́ ká gbé ẹjọ́ wa wá” (22-28) 
 
- 44  - 
- Ọlọ́run máa bù kún àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ (1-5) 
- Kò sí Ọlọ́run míì àfi Jèhófà (6-8) 
- Àwọn òrìṣà tí èèyàn ṣe kò já mọ́ nǹkan kan (9-20) 
- Jèhófà, Olùtúnrà Ísírẹ́lì (21-23) 
- Ipasẹ̀ Kírúsì ni wọ́n máa pa dà (24-28) 
 
- 45  - 
- Ọlọ́run yan Kírúsì pé kó ṣẹ́gun Bábílónì (1-8) 
- Amọ̀ ò lè bá Amọ̀kòkò fà á (9-13) 
- Àwọn orílẹ̀-èdè míì mọ Ísírẹ́lì (14-17) 
- Ọlọ́run ṣeé gbára lé lórí ọ̀rọ̀ ìṣẹ̀dá àti ṣíṣí nǹkan payá (18-25) 
 
- 46  
- 47  
- 48  - 
- Ọlọ́run bá Ísírẹ́lì wí, ó sì wẹ̀ ẹ́ mọ́ (1-11) 
- Jèhófà máa kọ lu Bábílónì (12-16a) 
- Ẹ̀kọ́ Ọlọ́run ṣàǹfààní (16b-19) 
- “Ẹ jáde kúrò ní Bábílónì!” (20-22) 
 
- 49  
- 50  
- 51  
- 52  
- 53  
- 54  
- 55  
- 56  
- 57  - 
- Olódodo àti àwọn olóòótọ́ ṣègbé (1, 2) 
- Àgbèrè ẹ̀sìn tí Ísírẹ́lì ń ṣe hàn síta (3-13) 
- A tu àwọn ẹni rírẹlẹ̀ nínú (14-21) 
 
- 58  
- 59  - 
- Àwọn ẹ̀ṣẹ̀ Ísírẹ́lì mú kí wọ́n jìnnà sí Ọlọ́run (1-8) 
- Wọ́n jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ (9-15a) 
- Jèhófà dá sí i torí àwọn tó ronú pìwà dà (15b-21) 
 
- 60  
- 61  
- 62  
- 63  - 
- Jèhófà máa gbẹ̀san lára àwọn orílẹ̀-èdè (1-6) 
- Bí Jèhófà ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn nígbà àtijọ́ (7-14) 
- Àdúrà ìrònúpìwàdà (15-19) 
 
- 64  
- 65  
- 66  - 
- Ìjọsìn tòótọ́ àti ìjọsìn èké (1-6) 
- Síónì tó jẹ́ ìyá àti àwọn ọmọ rẹ̀ (7-17) 
- Àwọn èèyàn kóra jọ láti jọ́sìn ní Jerúsálẹ́mù (18-24)