LÉFÍTÍKÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
 1 
 
 2 
 
 3 
 
 4 
 
 5 
Àwọn ẹ̀ṣẹ̀ pàtó àti ọrẹ tí ẹni tó ṣẹ̀ máa mú wá (1-6)
 
Ọrẹ tí àwọn aláìní máa mú wá (7-13)
 
Ẹbọ ẹ̀bi fún ẹ̀ṣẹ̀ àìmọ̀ọ́mọ̀dá (14-19)
 
 
 6 
 
 7 
Ìtọ́ni nípa àwọn ọrẹ (1-21)
 
Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ọ̀rá tàbí ẹ̀jẹ̀ (22-27)
 
Ìpín àlùfáà (28-36)
 
Ọ̀rọ̀ ìparí nípa àwọn ọrẹ (37, 38)
 
 
 8 
 
 9 
 
10 
Iná bọ́ látọ̀dọ̀ Jèhófà, ó sì pa Nádábù àti Ábíhù (1-7)
 
Ìlànà tí àwọn àlùfáà yóò máa tẹ̀ lé nípa jíjẹ àti mímu (8-20)
 
 
11 
 
12 
 
13 
 
14 
 
15 
 
16 
 
17 
Àgọ́ ìjọsìn, ibi tí wọ́n ti ń rúbọ (1-9)
 
Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀ (10-14)
 
Ìlànà nípa àwọn ẹran tó ti kú (15, 16)
 
 
18 
 
19 
 
20 
Ìjọsìn Mólékì; ìbẹ́mìílò (1-6)
 
Ẹ jẹ́ mímọ́ kí ẹ sì bọ̀wọ̀ fún àwọn òbí (7-9)
 
Ikú tọ́ sí àwọn oníṣekúṣe (10-21)
 
Ẹ jẹ́ mímọ́ kí ẹ lè wà ní ilẹ̀ náà (22-26)
 
Ikú tọ́ sí àwọn abẹ́mìílò (27)
 
 
21 
Kí àwọn àlùfáà jẹ́ mímọ́ kí wọ́n má sì di ẹlẹ́gbin (1-9)
 
Àlùfáà àgbà ò gbọ́dọ̀ sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́ (10-15)
 
Àwọn àlùfáà ò gbọ́dọ̀ ní àbùkù kankan lára (16-24)
 
 
22 
 
23 
 
24 
 
25 
Ọdún Sábáàtì (1-7)
 
Ọdún Júbílì (8-22)
 
Dídá ohun ìní pa dà (23-34)
 
Bí ẹ ṣe máa ṣe sí aláìní (35-38)
 
Òfin nípa ìfiniṣẹrú (39-55)
 
 
26 
 
27 
Ríra ohun téèyàn jẹ́jẹ̀ẹ́ rẹ̀ pa dà (1-27)
 
Àwọn ohun téèyàn yà sọ́tọ̀ pátápátá fún Jèhófà (28, 29)
 
Ríra ìdá mẹ́wàá pa dà (30-34)