NỌ́ŃBÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
 1 
Wọ́n forúkọ àwọn tó lè dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun sílẹ̀ (1-46)
 
Àwọn ọmọ Léfì ò ní wọṣẹ́ ológun (47-51)
 
Bí wọ́n á ṣe pàgọ́ wọn létòlétò (52-54)
 
 
 2 
 
 3 
 
 4 
Iṣẹ́ àwọn ọmọ Kóhátì (1-20)
 
Iṣẹ́ àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì (21-28)
 
Iṣẹ́ àwọn ọmọ Mérárì (29-33)
 
Àròpọ̀ iye àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ (34-49)
 
 
 5 
Yíya àwọn aláìmọ́ sọ́tọ̀ (1-4)
 
Ìjẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti sísan nǹkan dípò (5-10)
 
Lílo omi láti mọ̀ bóyá ẹnì kan ti ṣe àgbèrè (11-31)
 
 
 6 
 
 7 
 
 8 
Áárónì tan fìtílà méje (1-4)
 
Wọ́n wẹ àwọn ọmọ Léfì mọ́, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ (5-22)
 
Ọjọ́ orí àwọn ọmọ Léfì tó lè ṣiṣẹ́ (23-26)
 
 
 9 
 
10 
Kàkàkí tí wọ́n fi fàdákà ṣe (1-10)
 
Wọ́n kúrò ní Sínáì (11-13)
 
Bí wọ́n ṣe máa tò tẹ̀ léra tí wọ́n bá ń lọ (14-28)
 
Mósè ní kí Hóbábù fi ọ̀nà han Ísírẹ́lì (29-34)
 
Àdúrà Mósè tí wọ́n bá ń tú àgọ́ ká (35, 36)
 
 
11 
Iná bọ́ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run torí wọ́n ń ráhùn (1-3)
 
Wọ́n ń sunkún torí wọ́n fẹ́ jẹ ẹran (4-9)
 
Mósè wò ó pé òun ò kúnjú ìwọ̀n (10-15)
 
Jèhófà fi ẹ̀mí sára 70 àgbààgbà (16-25)
 
Ẹ́lídádì àti Médádì; Jóṣúà ń jowú torí Mósè (26-30)
 
Àwọn ẹyẹ àparò wá; Ọlọ́run fìyà jẹ wọ́n torí ìwọra wọn (31-35)
 
 
12 
 
13 
 
14 
Wọ́n fẹ́ pa dà sí Íjíbítì (1-10)
 
Jèhófà bínú; Mósè bá wọn bẹ̀bẹ̀ (11-19)
 
Ìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn: 40 ọdún nínú aginjù (20-38)
 
Àwọn ọmọ Ámálékì ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (39-45)
 
 
15 
Òfin nípa ọrẹ (1-21)
 
Ọrẹ tí ẹni tó bá ṣèèṣì dẹ́ṣẹ̀ máa mú wá (22-29)
 
Ìyà tó máa jẹ ẹni tó bá mọ̀ọ́mọ̀ dẹ́ṣẹ̀ (30, 31)
 
Wọ́n pa ẹni tó rú òfin Sábáàtì (32-36)
 
Kí wọ́n máa ṣe wajawaja sí etí aṣọ wọn (37-41)
 
 
16 
 
17 
 
18 
Ojúṣe àwọn àlùfáà àtàwọn ọmọ Léfì (1-7)
 
Ìpín àwọn àlùfáà (8-19)
 
Kí àwọn ọmọ Léfì máa gba ìdá mẹ́wàá, kí wọ́n sì máa san án (20-32)
 
 
19 
 
20 
 
21 
Wọ́n ṣẹ́gun ọba Árádì (1-3)
 
Ejò tí wọ́n fi bàbà ṣe (4-9)
 
Ísírẹ́lì lọ yí ká Móábù (10-20)
 
Wọ́n ṣẹ́gun Síhónì ọba àwọn Ámórì (21-30)
 
Wọ́n ṣẹ́gun Ógù ọba àwọn Ámórì (31-35)
 
 
22 
 
23 
 
24 
 
25 
 
26 
 
27 
 
28 
 
29 
 
30 
 
31 
 
32 
 
33 
 
34 
 
35 
Ìlú àwọn ọmọ Léfì (1-8)
 
Àwọn ìlú ààbò (9-34)
 
 
36