MÁTÍÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  
-  2  - 
- Àwọn awòràwọ̀ wá (1-12) 
- Wọ́n sá lọ sí Íjíbítì (13-15) 
- Hẹ́rọ́dù pa àwọn ọmọdékùnrin (16-18) 
- Wọ́n pa dà sí Násárẹ́tì (19-23) 
 
-  3  
-  4  - 
- Èṣù dán Jésù wò (1-11) 
- Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù ní Gálílì (12-17) 
- Ó pe àwọn ọmọ ẹ̀yìn àkọ́kọ́ (18-22) 
- Jésù ń wàásù, ó ń kọ́ni, ó sì ń woni sàn (23-25) 
 
-  5  - 
- ÌWÀÁSÙ ORÍ ÒKÈ (1-48) - 
- Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ni lórí òkè (1, 2) 
- Ohun mẹ́sàn-án tó ń múni láyọ̀ (3-12) 
- Iyọ̀ àti ìmọ́lẹ̀ (13-16) 
- Jésù máa mú Òfin ṣẹ (17-20) 
- Ìmọ̀ràn lórí ìbínú (21-26), àgbèrè (27-30), ìkọ̀sílẹ̀ (31, 32), ìbúra (33-37), ẹ̀san (38-42), nínífẹ̀ẹ́ àwọn ọ̀tá (43-48) 
 
 
-  6  
-  7  
-  8  - 
- Ó wo adẹ́tẹ̀ sàn (1-4) 
- Ọ̀gágun fi hàn pé òun nígbàgbọ́ (5-13) 
- Jésù wo ọ̀pọ̀ èèyàn sàn ní Kápánáúmù (14-17) 
- Bí a ṣe lè tẹ̀ lé Jésù (18-22) 
- Jésù mú kí ìjì dáwọ́ dúró (23-27) 
- Jésù lé àwọn ẹ̀mí èṣù lọ sínú àwọn ẹlẹ́dẹ̀ (28-34) 
 
-  9  - 
- Jésù wo alárùn rọpárọsẹ̀ sàn (1-8) 
- Jésù pe Mátíù (9-13) 
- Ìbéèrè nípa ààwẹ̀ gbígbà (14-17) 
- Ọmọbìnrin Jáírù; obìnrin kan fọwọ́ kan aṣọ àwọ̀lékè Jésù (18-26) 
- Jésù wo afọ́jú àti ẹni tí kò lè sọ̀rọ̀ sàn (27-34) 
- Ìkórè pọ̀, àmọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ò tó nǹkan (35-38) 
 
- 10  - 
- Àwọn àpọ́sítélì méjìlá (1-4) 
- Ìtọ́ni tó wà fún iṣẹ́ ìwàásù (5-15) 
- Wọ́n máa ṣe inúnibíni sí àwọn ọmọ ẹ̀yìn (16-25) 
- Ẹ bẹ̀rù Ọlọ́run, ẹ má bẹ̀rù èèyàn (26-31) 
- Mo wá láti mú idà wá, kì í ṣe àlàáfíà (32-39) 
- Gbígba àwọn ọmọ ẹ̀yìn (40-42) 
 
- 11  - 
- Ó yin Jòhánù Arinibọmi (1-15) 
- Ó dẹ́bi fún ìran aláìgbọràn (16-24) 
- Jésù yin Bàbá rẹ̀ torí pé ó ṣojúure sí àwọn tó rẹlẹ̀ (25-27) 
- Àjàgà Jésù ń tuni lára (28-30) 
 
- 12  - 
- Jésù ni “Olúwa Sábáàtì” (1-8) 
- Ó wo ọkùnrin tí ọwọ́ rẹ̀ rọ sàn (9-14) 
- Ìránṣẹ́ tí Ọlọ́run fẹ́ràn (15-21) 
- Ó fi ẹ̀mí mímọ́ lé ẹ̀mí èṣù jáde (22-30) 
- Ẹ̀ṣẹ̀ tí kò ní ìdáríjì (31, 32) 
- Èso igi la fi máa mọ̀ ọ́n (33-37) 
- Àmì Jónà (38-42) 
- Tí ẹ̀mí àìmọ́ bá pa dà wá (43-45) 
- Ìyá Jésù àtàwọn arákùnrin rẹ̀ (46-50) 
 
- 13  
- 14  - 
- Wọ́n gé orí Jòhánù Arinibọmi (1-12) 
- Jésù bọ́ 5,000 èèyàn (13-21) 
- Jésù rìn lórí omi (22-33) 
- Ó ṣèwòsàn ní Jẹ́nẹ́sárẹ́tì (34-36) 
 
- 15  - 
- Ó tú àṣírí àwọn àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ (1-9) 
- Inú ọkàn ni ohun tó ń sọni di aláìmọ́ ti ń wá (10-20) 
- Ìgbàgbọ́ obìnrin ará Foníṣíà lágbára gan-an (21-28) 
- Jésù wo ọ̀pọ̀ àìlera sàn (29-31) 
- Jésù bọ́ 4,000 èèyàn (32-39) 
 
- 16  - 
- Wọ́n ń wá àmì (1-4) 
- Ìwúkàrà àwọn Farisí àti Sadusí (5-12) 
- Àwọn kọ́kọ́rọ́ Ìjọba náà (13-20) 
- Àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú Jésù (21-23) 
- Bí a ṣe lè jẹ́ ọmọ ẹ̀yìn tòótọ́ (24-28) 
 
- 17  - 
- Ìyípadà ológo (1-13) 
- Ìgbàgbọ́ bíi hóró músítádì (14-21) 
- Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (22, 23) 
- Wọ́n fi owó ẹnu ẹja san owó orí (24-27) 
 
- 18  - 
- Ẹni tó tóbi jù nínú Ìjọba náà (1-6) 
- Àwọn ohun ìkọ̀sẹ̀ (7-11) 
- Àpèjúwe àgùntàn tó sọ nù (12-14) 
- Bí o ṣe lè jèrè arákùnrin (15-20) 
- Àpèjúwe ẹrú tí kò dárí jini (21-35) 
 
- 19  - 
- Ìgbéyàwó àti ìkọ̀sílẹ̀ (1-9) 
- Ẹ̀bùn wíwà láìlọ́kọ tàbí láìláya (10-12) 
- Jésù súre fún àwọn ọmọdé (13-15) 
- Ìbéèrè ọ̀dọ́kùnrin ọlọ́rọ̀ (16-24) 
- Àwọn ohun tí a fi sílẹ̀ nítorí Ìjọba náà (25-30) 
 
- 20  - 
- Àwọn òṣìṣẹ́ ọgbà àjàrà gba iye owó kan náà (1-16) 
- Jésù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (17-19) 
- Wọ́n ń wá ipò nínú Ìjọba náà (20-28) 
- Ó wo ọkùnrin afọ́jú méjì sàn (29-34) 
 
- 21  - 
- Jésù wọ Jerúsálẹ́mù tiyì-tẹ̀yẹ (1-11) 
- Jésù fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (12-17) 
- Ó gégùn-ún fún igi ọ̀pọ̀tọ́ (18-22) 
- Wọ́n béèrè àṣẹ tí Jésù fi ń ṣe nǹkan (23-27) 
- Àpèjúwe àwọn ọmọ méjì (28-32) 
- Àpèjúwe àwọn tó ń dáko, tí wọ́n sì pààyàn (33-46) 
 
- 22  - 
- Àpèjúwe ayẹyẹ ìgbéyàwó (1-14) 
- Ọlọ́run àti Késárì (15-22) 
- Ìbéèrè nípa àjíǹde (23-33) 
- Àṣẹ méjì tó tóbi jù (34-40) 
- Ṣé ọmọ Dáfídì ni Kristi? (41-46) 
 
- 23  - 
- Ẹ má tẹ̀ lé àpẹẹrẹ àwọn akọ̀wé òfin àtàwọn Farisí (1-12) 
- Àwọn akọ̀wé òfin àtàwọn Farisí gbé (13-36) 
- Jésù dárò lórí Jerúsálẹ́mù (37-39) 
 
- 24  
- 25  
- 26  - 
- Àwọn àlùfáà gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù (1-5) 
- Ó da òróró onílọ́fínńdà sára Jésù (6-13) 
- Ìrékọjá tó gbẹ̀yìn àti ẹni tó máa da Jésù (14-25) 
- Jésù fi Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa lọ́lẹ̀ (26-30) 
- Ó sọ tẹ́lẹ̀ pé Pétérù máa sẹ́ òun (31-35) 
- Jésù gbàdúrà ní Gẹ́tísémánì (36-46) 
- Wọ́n mú Jésù (47-56) 
- Wọ́n gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (57-68) 
- Pétérù sẹ́ Jésù (69-75) 
 
- 27  - 
- Wọ́n fa Jésù lé Pílátù lọ́wọ́ (1, 2) 
- Júdásì pokùnso (3-10) 
- Jésù dé iwájú Pílátù (11-26) 
- Wọ́n fi ṣẹlẹ́yà ní gbangba (27-31) 
- Wọ́n kàn án mọ́gi ní Gọ́gọ́tà (32-44) 
- Ikú Jésù (45-56) 
- Wọ́n sìnkú Jésù (57-61) 
- Wọ́n sé ibojì rẹ̀ mọ́ (62-66) 
 
- 28