B14-B
Owó àti Ìdíwọ̀n
Owó àti Ìdíwọ̀n Nínú Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù
| Gérà (Ṣékélì 1⁄20) Gíráàmù 0.57 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.01835 Gérà 10 = Bíkà 1 | 
| Bíkà Gíráàmù 5.7 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.1835 Bíkà 2 = Ṣékélì 1 | 
| Píìmù Gíráàmù 7.8 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.2508 Píìmù 1 = Ṣékélì 2⁄3 | 
| Ìdíwọ̀n ṣékélì Ṣékélì Gíráàmù 11.4 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.367 Ṣékélì 50 = Mínà 1 | 
| Mínà Gíráàmù 570 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 18.35 Mínà 60 = Tálẹ́ńtì 1 | 
| Tálẹ́ńtì Kìlógíráàmù 34.2 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 1,101 | 
| Dáríkì (ti Páṣíà, wúrà) Gíráàmù 8.4 / 0.27 Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì | 
Owó àti Ìdíwọ̀n Nínú Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì
| Lẹ́pítónì (Ti àwọn Júù, bàbà tàbí idẹ) Kúádíránì 1⁄2 | 
| Kúádíránì (Ti àwọn ará Róòmù, bàbà tàbí idẹ) Lẹ́pítónì 2 | 
| Ásáríò (Ti àwọn Róòmù àtàwọn ìlú abẹ́ wọn, bàbà tàbí idẹ) Kúádíránì 4 | 
| Dínárì (Ti àwọn Róòmù, fàdákà) Kúádíránì 64 Gíráàmù 3.85 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.124 = Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 1 (Wákàtí 12) | 
| Dírákímà (Ti àwọn Gíríìkì, fàdákà) Gíráàmù 3.4 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.109 = Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 1 (12 hours) | 
| Dírákímà méjì alápapọ̀ (Ti àwọn Gíríìkì, fàdákà) Dírákímà 2 Gíráàmù 6.8 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.218 = Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 2 | 
| Dírákímà mẹ́rin alápapọ̀ ti Tírè (Ṣékélì fàdákà ti Tírè) Dírákímà mẹ́rin alápapọ̀ (Ti àwọn Gíríìkì, fàdákà; wọ́n tún ń pè é ní owó sítátà fàdákà) Dírákímà 4 Gíráàmù 13.6 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.436 = Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 4 | 
| Mínà Dírákímà 100 Gíráàmù 340 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 10.9 = nǹkan bí owó iṣẹ́ 100 ọjọ́ | 
| Tálẹ́ńtì Mínà 60 Kìlógíráàmù 20.4 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 654 = nǹkan bí owó iṣẹ́ 20 ọdún | 
| Ìwọ̀n Pọ́n-ùn (ti àwọn ará Róòmù) Gíráàmù 327 / Ọ́ǹsì 11.5 
 |