ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g03 7/8 ojú ìwé 32
  • Ǹjẹ́ Ọmọ Aráyé Ò Ní Pa Ilẹ̀ Ayé Wa Rírẹwà Yìí Run Báyìí?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ǹjẹ́ Ọmọ Aráyé Ò Ní Pa Ilẹ̀ Ayé Wa Rírẹwà Yìí Run Báyìí?
  • Jí!—2003
Jí!—2003
g03 7/8 ojú ìwé 32

Ǹjẹ́ Ọmọ Aráyé Ò Ní Pa Ilẹ̀ Ayé Wa Rírẹwà Yìí Run Báyìí?

Ǹjẹ́ Ọlọ́run á fàyè gba irú nǹkan bẹ́ẹ̀ kó ṣẹlẹ̀? O lè mọ̀ nípa ète dáradára tí Ọlọ́run ní fún ilẹ̀ ayé yìí nípa kíka ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé méjìlélọ́gbọ̀n tí àwòrán rẹ̀ wà nísàlẹ̀ yìí. Bó o bá fẹ́ láti rí ẹ̀dà kan ìwé pẹlẹbẹ yìí gbà, jọ̀wọ́ kàn sí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ládùúgbò rẹ. Bó o bá fẹ́ kí ẹnì kan wá ọ wá, jọ̀wọ́ kọ̀wé sínú fọ́ọ̀mù tó wà nísàlẹ̀ yìí kí o sì fi ránṣẹ́ sí àdírẹ́sì tá a kọ síbẹ̀ tàbí sí àdírẹ́sì tó bá yẹ lára èyí tá a tò sójú ìwé 5 nínú ìwé ìròyìn yìí.

□ Ẹ jọ̀wọ́, ẹ kàn sí mi nípa ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì inú ilé lọ́fẹ̀ẹ́.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́