Atọ́ka Ìdìpọ̀ Karùndínláàádọ́rùn-ún Ti jí!
ÀJỌṢE Ẹ̀DÁ
Bàbá Tó Dáa, 9/8
Ìgbà Ìbàlágà, 7/8
Ìṣòro Dídá Wà, 6/8
Kíkàwé Fáwọn Ọmọdé, 11/8
Kíkọ́ Ọmọ Láti Kékeré, 11/8
Lọ́rẹ̀ẹ́ Àtàtà, 12/8
Má Máa Pẹ́ Lẹ́yìn! 7/8
Nífẹ̀ẹ́ sí Ẹ̀kọ́ Kíkọ́, 8/8
Ohun Tí Àwọn Ọmọ Ọwọ́ Nílò Lọ́dọ̀ Àwọn Òbí, 1/8
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
A Dán Ìgbàgbọ́ Wọn Wò (Àwọn Mẹ́rìndínlógún Tí Wọ́n Fi Sẹ́wọ̀n Nílùú Richmond), 3/8
Aláàánú Ará Samáríà Òde Òní, 8/8
Àwọn Àpéjọ Àgbègbè “Ẹ Bá Ọlọ́run Rìn,” 9/8
‘Àwọn Àwòrán Yìí Nítumọ̀ Gan-an Ni’ (àwọn àwòrán inú ìtẹ̀jáde wa), 5/8
Àwọn Èwe Tí Wọn Ò Fi Ìgbàgbọ́ Wọn Bò, 9/8
Àwọn Jagunjagun Tẹ́lẹ̀ Tí Wọ́n Di Olùwá Àlàáfíà, 10/8
“Gbogbo Èèyàn Ló Yẹ Kó Kàwé Yìí O” (Olùkọ́), 12/8
Ìbẹ̀wò Mánigbàgbé (Mẹ́síkò), 3/8
Ìgbàgbọ́ Ran Ìdílé Kan Lọ́wọ́ Nígbà Ìpọ́njú, 5/8
Ilé Ẹjọ́ Ilẹ̀ Yúróòpù Fún Ìyá Kan Ní Ẹ̀tọ́ Rẹ̀, (Ilẹ̀ Faransé), 12/8
“Kò Yẹ Kí Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìlú Gbófin Tara Ẹ̀ Kalẹ̀” (Kánádà), 7/8
Mi Ò Jẹ́ Mu Sìgá! (ewì tí ọmọbìnrin kan kọ), 5/8
Mímú Òtítọ́ Bíbélì Dé Ọ̀dọ̀ Àwọn Kúrékùré (Orílẹ̀-èdè Cameroon), 9/8
ÀWỌN OHUN TÓ Ń ṢẸLẸ̀ NÍNÚ AYÉ
Àtúntò, 4/8
Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Wọ́n Lù Ọ́ Ní Jìbìtì, 8/8
Ẹ̀tanú, 9/8
Ilẹ̀ Ayé Wa Lọ́jọ́ Iwájú, 2/8
Ìrọ́kẹ̀kẹ̀ Ogun Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé, 3/8
Oyún Ọ̀dọ́langba, 10/8
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Agbo Ijó Alẹ́, 5/8
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Di Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ Tó Dáńgájíá? 1/8
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ráyè Ṣe Iṣẹ́ Àṣetiléwá Mi? 2/8
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Sọ Ohun Tó Wà Lọ́kàn Mi fún Un? 11/8
Ìbálòpọ̀ Ṣáájú Ìgbéyàwó, 8/8, 9/8
Jíjíròrò Nípa Ìbálòpọ̀ Lórí Tẹlifóònù, 3/8
Kí Ló Burú Nínú Mímutí Àmuyíràá? 10/8
Kí Ló Fà Á Tó Fi Ń Hu Irú Ìwà Yìí sí Mi? 6/8
Kí Ni Kí N Ṣe Nígbà Tí Mo Bá Kùnà? 12/8
Kí Ni Mo Lè Ṣe Láti Mú Kí Ọ̀rẹ́kùnrin Mi Dẹ́kun Fífìyà Jẹ Mí? 7/8
Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Ń Jẹ́ Ká Jìyà? 4/8
ÈTÒ ỌRỌ̀ AJÉ ÀTI IṢẸ́
Bí Wọ́n Bá Dájú Sọ Ọ́ Níbi Iṣẹ́, 5/8
ẸRANKO ÀTI OHUN Ọ̀GBÌN
Àǹfààní Tí À Ń Rí Nínú Igbó, 3/8
Ṣé Nítorí Àtiṣoge Nìkan Ni? (báwọn ẹyẹ ṣe ń fi àgógó túnra ṣe), 5/8
ÌLERA ÀTI ÌṢÈGÙN
Àìkìísùntó, 2/8
Aráyé Ń Gbógun Ti Àrùn, 6/8
Àrùn Ọpọlọ, 10/8
Bí Àníyàn Nípa Ìrísí Bá Gbani Lọ́kàn Ju Bó Ṣe Yẹ Lọ, 8/8
Bí Ìgbàgbọ́ Ṣe Ran Ìdílé Kan Lọ́wọ́ (àrùn tó máa ń dégbò sára ìtẹ́nú ìwọ́rọ́kù), 5/8
Bí Ọmọ Rẹ Bá Ń Ké Ṣáá, 5/8
Ewé àti Egbò, 1/8
Ìgbà Wo Làrùn Éèdì Ò Ní Sí Mọ́? 12/8
Kéèyàn Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀, 11/8
Kí Ìṣesí Máa Ṣàdédé Yí Padà, 1/8
Kí Nìdí Tá A Fi Nílò Ìrètí? 5/8
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Fi Ìrìn Rírìn Ṣe Eré Ìmárale? 3/8
Ọ̀fìnkìn Tí Nǹkan Tó Ń Kù Ń Fà, 6/8
ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈNÌYÀN
Orúkọ Ọlọ́run Lára Àwọn Ilé Àtayébáyé (Slovenia), 2/8
Ọjà Ẹja Tó Tóbi Jù Lọ Lágbàáyé (Japan), 3/8
Ọjọ́ Tí “Olú Ìlú Ọsirélíà Tí Igi Pọ̀ Sí” Jóná (Ọsirélíà), 3/8
Wọ́n Bọ́ Lọ́wọ́ Ewu Omíyalé! (Switzerland), 4/8
ÌSÌN
Bí O Ṣe Lè Mọ Orúkọ Ọlọ́run, 2/8
Bíbélì Geneva, 9/8
Orúkọ Ọlọ́run Lára Àwọn Ilé Àtayébáyé, 2/8
Ṣé Mósè Ti Gbáyé Rí àbí Ẹni Ìtàn Àròsọ Ni? 4/8
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Àtikékeré Ni Wọ́n Ti Kọ́ Mi Láti Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run (A. Melnik), 11/8
Àwọn Ìnira Ìgbà Ogun Mú Mi Gbára Dì fún Bá A Ṣeé Gbé Ìgbésí Ayé (E. Krömer), 7/8
Bí A Ṣe Kọ́ Kristi Láti Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run (H. Forbes), 4/8
Ìdí Tí Mo Fi Gba Bíbélì Gbọ́—Onímọ̀ Nípa Agbára Átọ́míìkì (A. Williams), 7/8
Ìmúra àti Ìwọṣọ Ni Kò Jẹ́ Kí N Tètè Rí Òtítọ́ (E. Brumbaugh), 3/8
“Jèhófà, O Wá Mi Kàn!” (N. Lenz), 10/8
Ohun Tó Sàn Ju Lílókìkí Nínú Ayé (C. Sinutko), 10/8
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Hùwà sí Àwọn Àgbàlagbà? 10/8
Béèyàn Ṣe Lè Sá fún Ewu Tó Wà Nínú Lílo Íńtánẹ́ẹ̀tì, 12/8
Fífi Ìbáwí Ọlọ́run Tọ́ Àwọn Ọmọ, 11/8
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ka Ìgbéyàwó sí Ohun Mímọ́? 5/8
Ǹjẹ́ Ó Ṣeé Ṣe Láti Jáwọ́ Nínú Àṣà Burúkú? 4/8
Ǹjẹ́ Ọgbọ́n Ìṣèlú Lè Mú Àlàáfíà Kárí Ayé Wá? 1/8
Olórí Ìdílé, 7/8
Ọlọ́run Bìkítà Nípa Àwọn Ọmọdé? 8/8
Ṣé Bẹ́ẹ̀ Náà Ni Ọtí Àmujù Burú Tó Ni? 3/8
Ṣé Ẹní Bá Ń Ṣàníyàn Ò Nígbàgbọ́ Ni? 6/8
Ṣé Ìkọ̀sílẹ̀ Ló Máa Yanjú Ìṣòro Yín? 9/8
Ṣé Irú Ẹ̀jẹ̀ Rẹ Ló Ń Sọ Irú Ẹni Tó O Jẹ́? 2/8
Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN
Àwọn Ohun Ìṣeré Tó Dáa Jù Lọ, 8/8
Dídúró Gbọn-in Nígbà Ìṣòro, 2/8
Ìfẹ́ Láti Kẹ́kọ̀ọ́, 8/8
Ilé Ìwé Jẹ́lé-Ó-Sinmi Tí Kò Ní Ohun Ìṣeré Ọmọdé, 10/8
Ìrètí, 5/8
Iṣẹ́ Ọwọ́ Ẹlẹ́dàá Ni Wọ́n Wò Ṣe É (gílóòbù), 1/8
Ǹjẹ́ O Mọ̀? 2/8, 4/8, 6/8, 8/8, 10/8, 12/8
Ó Yẹ Ká Kó Ahọ́n Wa Níjàánu Bíi Tẹṣin, 6/8
SÁYẸ́ǸSÌ
Ìdí Tí Mo Fi Gba Bíbélì Gbọ́—Onímọ̀ Nípa Agbára Átọ́míìkì, 7/8