Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Jí! 2017
Jí! ni ìwé ìròyìn tó dá lórí oríṣiríṣi nǹkan tó sì délé-dóko jù lọ láyé!
Ó lé ní 360 mílíọ̀nù ẹ̀dà tá à ń tẹ̀ ní ohun tó ju ọgọ́rùn-ún èdè lọ!
ÀJỌṢE ÀWỌN ÈÈYÀN
- Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Ní Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ (ọmọ títọ́): No. 6 
- Bó O Ṣe Lè Mọyì Ẹnì Kejì Rẹ (ìgbéyàwó): No. 1 
- Ẹ̀rín Músẹ́—Ẹ̀bùn Tó O Lè Fúnni: No. 1 
- Iṣẹ́ Ilé Ṣe Pàtàkì (ọmọ títọ́), No. 3 
- Kí Làwọn Èèyàn Ń Rí Nínú Eré Tó Léwu? (àwọn ọ̀dọ́): No. 5 
- Nígbà Tí Àwọn Ọmọ Bá Ti Kúrò Nílé (ìgbéyàwó): No. 4 
- Nígbà Tí Òbí Ẹnì Kan Bá Kú (àwọn ọ̀dọ́): No. 2 
- ‘Orúkọ Rere Dára Ju Ọ̀pọ̀ Yanturu Ọrọ̀ Lọ’: No. 4 
- Tí Òbí Ọmọdé Kan Bá Kú: No. 2 
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
- “Irú Ìfẹ́ Yìí Wú Wa Lórí Gan-an Ni” (ìmìtìtì ilẹ̀ lórílẹ̀-èdè Nepal): No. 1 
ÀWỌN ẸNI INÚ ÌTÀN
- Alhazen: No. 6 
ÀWỌN ẸRANKO ÀTI EWÉKO
- Ẹyẹ Arctic Tern: No. 4 
Ẹ̀SÌN
- Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Bíbélì Ti Wá Lóòótọ́? No. 3 
ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ
- Onímọ̀ Nípa Àrùn Ọpọlọ Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́ (Rajesh Kalaria): No. 4 
- Onímọ̀ Nípa Ètò Orí Kọ̀ǹpútà Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́ (Dr. Fan Yu): No. 3 
ÌLERA ÀTI ÌTỌ́JÚ
- Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ní Ìdààmú Ọkàn: No. 1 
ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈÈYÀN
OHUN TÓ Ń LỌ LÁYÉ
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
- Bó O Ṣe Lè Máa Ṣọ́ Nǹkan Lò: No. 5 
- Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Agbára Abàmì No. 2 
- Ṣé Ọwọ́ Rẹ Máa Ń Dí Jù? No. 4