ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 8A
Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà—Igi Kédárì Ńlá
Bíi Ti Orí Ìwé
	ÌSÍKÍẸ́LÌ 17:3-24
- 1. Nebukadinésárì mú Jèhóákínì lọ sí Bábílónì 
- 2. Nebukadinésárì fi Sedekáyà sórí ìtẹ́ ní Jerúsálẹ́mù 
- 3. Sedekáyà ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà, ó wá ìrànlọ́wọ́ lọ sí Íjíbítì nígbà tó fẹ́ jagun 
- 4. Jèhófà gbin Ọmọ rẹ̀ sórí Òkè Síónì ní ọ̀run 
- 5. Lábẹ́ òjìji Ìjọba Jésù, àwọn èèyàn tí wọ́n jẹ́ onígbọràn máa gbé lábẹ́ ààbò