ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 10A
Ìjọsìn Mímọ́—Pa Dà Bọ̀ Sípò Díẹ̀díẹ̀
Bíi Ti Orí Ìwé
	- ‘Ariwo tó dà bí ìgbà tí nǹkan ń rọ́ gììrì’ - William Tyndale àtàwọn míì túmọ̀ Bíbélì sí èdè Gẹ̀ẹ́sì àtàwọn èdè míì 
- “Iṣan àti ẹran” - Charles T. Russell àtàwọn alábàákẹ́gbẹ́ rẹ̀ mú káwọn èèyàn lóye òtítọ́ Bíbélì 
- “Wọ́n wá di alààyè, wọ́n sì dìde dúró” - Lẹ́yìn táwọn èèyàn Jèhófà “di alààyè” lọ́dún 1919, wọ́n túbọ̀ tẹra mọ́ iṣẹ́ ìwàásù wọn