ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 22A
Ìdánwò Ìkẹyìn Tí Aráyé Máa Dojú Kọ
Bíi Ti Orí Ìwé
	- Àwọn Èèyàn Á Di Ẹni Pípé—1 KỌ́R. 15:26 
- Jésù Dá Ìjọba Pa Dà fún Jèhófà—1 KỌ́R. 15:24 
- A Tú Sátánì Sílẹ̀ Kúrò Nínú Ọ̀gbun Àìnísàlẹ̀; Àwọn Ọlọ̀tẹ̀ Dara Pọ̀ Mọ́ Sátánì Láti Jagun Àjàkẹ́yìn—ÌFI. 20:3, 7, 8 
- Gbogbo Àwọn Ọlọ̀tẹ̀ Pa Run—ÌFI. 20:9, 10, 15 
- Ìyè Àìnípẹ̀kun Nínú Ayé Tuntun Tí Ìṣọ̀kan àti Àlàáfíà Ti Ń Jọba—RÓÒMÙ 8:19-21