Jẹ́nẹ́sísì 40:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọjọ́ kẹta wá jẹ́ ọjọ́ ìbí+ Fáráò, ó sì se àsè fún gbogbo ìránṣẹ́ rẹ̀, ó wá mú olórí agbọ́tí àti olórí alásè jáde* níṣojú àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. 21 Ó dá olórí agbọ́tí pa dà sí ipò tó wà tẹ́lẹ̀, ó sì ń gbé ife fún Fáráò.
20 Ọjọ́ kẹta wá jẹ́ ọjọ́ ìbí+ Fáráò, ó sì se àsè fún gbogbo ìránṣẹ́ rẹ̀, ó wá mú olórí agbọ́tí àti olórí alásè jáde* níṣojú àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. 21 Ó dá olórí agbọ́tí pa dà sí ipò tó wà tẹ́lẹ̀, ó sì ń gbé ife fún Fáráò.