Máàkù 6:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àmọ́ àyè ṣí sílẹ̀ ní ọjọ́ tí Hẹ́rọ́dù ń ṣe ọjọ́ ìbí rẹ̀.+ Ó se àsè oúnjẹ alẹ́ fún àwọn ìjòyè rẹ̀, àwọn ọ̀gágun àti àwọn ọkùnrin tó gbajúmọ̀ jù ní Gálílì.+
21 Àmọ́ àyè ṣí sílẹ̀ ní ọjọ́ tí Hẹ́rọ́dù ń ṣe ọjọ́ ìbí rẹ̀.+ Ó se àsè oúnjẹ alẹ́ fún àwọn ìjòyè rẹ̀, àwọn ọ̀gágun àti àwọn ọkùnrin tó gbajúmọ̀ jù ní Gálílì.+