ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 40:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Wọ́n fèsì pé: “Kálukú wa lá àlá, àmọ́ kò sẹ́ni tó máa túmọ̀ rẹ̀ fún wa.” Jósẹ́fù sọ fún wọn pé: “Ṣebí Ọlọ́run+ ló ni ìtúmọ̀? Ẹ jọ̀ọ́, ẹ rọ́ àlá yín fún mi.”

  • Dáníẹ́lì 2:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ìwọ Ọlọ́run àwọn baba ńlá mi, ni mò ń dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, tí mo sì ń fìyìn fún,

      Torí o ti fún mi ní ọgbọ́n àti agbára.

      O sì ti wá jẹ́ kí n mọ ohun tí a béèrè lọ́wọ́ rẹ;

      O ti jẹ́ ká mọ ohun tó ń da ọba láàmú.”+

  • Dáníẹ́lì 2:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Àmọ́ Ọlọ́run kan wà ní ọ̀run, tó jẹ́ Ẹni tó ń ṣí àwọn àṣírí payá,+ ó sì ti jẹ́ kí Ọba Nebukadinésárì mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ ní apá ìgbẹ̀yìn àwọn ọjọ́. Àlá rẹ nìyí, àwọn ìran tí o sì rí nígbà tí o dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn rẹ nìyí:

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́