-
Nọ́ńbà 1:34, 35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Wọ́n fi orúkọ wọn, ìdílé wọn àti agbo ilé bàbá wọn to àwọn àtọmọdọ́mọ Mánásè.+ Gbogbo ọkùnrin tó jẹ́ ẹni ogún (20) ọdún sókè, tó lè dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun ni wọ́n kà, 35 iye àwọn tí wọ́n sì forúkọ wọn sílẹ̀ nínú ẹ̀yà Mánásè jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà méjìlélọ́gbọ̀n ó lé igba (32,200).
-