-
Jẹ́nẹ́sísì 45:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Èmi yóò máa fún ọ ní oúnjẹ níbẹ̀, torí ó ṣì ku ọdún márùn-ún tí ìyàn+ á fi mú. Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ìwọ àti ilé rẹ máa di aláìní àti gbogbo ohun tí o ní.”’
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 47:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Torí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í mú ẹran ọ̀sìn wọn wá fún Jósẹ́fù. Jósẹ́fù ń gba ẹṣin, agbo ẹran, ọ̀wọ́ ẹran àti àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọn, ó sì ń fún àwọn èèyàn náà ní oúnjẹ. Ó ń fún wọn ní oúnjẹ dípò gbogbo ẹran ọ̀sìn wọn tó gbà lọ́dún yẹn.
-