Jẹ́nẹ́sísì 47:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kò sí oúnjẹ* ní gbogbo ilẹ̀ náà torí ìyàn náà mú gidigidi, ìyàn+ náà mú kí oúnjẹ tán pátápátá ní ilẹ̀ Íjíbítì àti Kénáánì.
13 Kò sí oúnjẹ* ní gbogbo ilẹ̀ náà torí ìyàn náà mú gidigidi, ìyàn+ náà mú kí oúnjẹ tán pátápátá ní ilẹ̀ Íjíbítì àti Kénáánì.