-
Jẹ́nẹ́sísì 41:57Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
57 Àwọn èèyàn láti ibi gbogbo sì ń lọ sí Íjíbítì kí wọ́n lè ra oúnjẹ lọ́dọ̀ Jósẹ́fù torí ìyàn náà mú gidigidi ní gbogbo ilẹ̀.+
-
-
Ìṣe 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àmọ́ ìyàn kan mú ní gbogbo Íjíbítì àti Kénáánì, ìpọ́njú ńlá ni, àwọn baba ńlá wa ò sì rí nǹkan kan jẹ.+
-