-
Jẹ́nẹ́sísì 43:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ọkùnrin náà sọ fún wọn pé: “Ó dáa. Ẹ má bẹ̀rù. Ọlọ́run yín àti Ọlọ́run bàbá yín ló fi ìṣúra sínú àpò yín. Èmi ni mo kọ́kọ́ gba owó yín.” Lẹ́yìn náà, ó mú Síméónì jáde wá bá wọn.+
-