Jẹ́nẹ́sísì 42:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àmọ́ wọn ò mọ̀ pé Jósẹ́fù gbọ́ èdè wọn torí ògbufọ̀ ló ń túmọ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀. 24 Ló bá kúrò lọ́dọ̀ wọn, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sunkún.+ Nígbà tó pa dà sọ́dọ̀ wọn, tó sì tún bá wọn sọ̀rọ̀, ó mú Síméónì+ láàárín wọn, ó sì dè é níṣojú+ wọn.
23 Àmọ́ wọn ò mọ̀ pé Jósẹ́fù gbọ́ èdè wọn torí ògbufọ̀ ló ń túmọ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀. 24 Ló bá kúrò lọ́dọ̀ wọn, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sunkún.+ Nígbà tó pa dà sọ́dọ̀ wọn, tó sì tún bá wọn sọ̀rọ̀, ó mú Síméónì+ láàárín wọn, ó sì dè é níṣojú+ wọn.