ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 42:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ojú ẹsẹ̀ tí Jósẹ́fù rí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ló dá wọn mọ̀, àmọ́ kò jẹ́ kí wọ́n+ mọ̀ pé òun ni. Ó wá fi ohùn líle bá wọn sọ̀rọ̀, ó ní: “Ibo lẹ ti wá?” Wọ́n fèsì pé: “Ilẹ̀ Kénáánì la ti wá, ká lè ra oúnjẹ.”+

  • Jẹ́nẹ́sísì 42:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Jósẹ́fù rántí àwọn àlá tó lá nípa wọn, ó sì sọ fún wọn+ pé: “Amí ni yín! Ṣe lẹ wá wo ibi tí ẹ ti lè gbógun ja ilẹ̀ wa!”*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́