Jẹ́nẹ́sísì 42:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ló bá kúrò lọ́dọ̀ wọn, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sunkún.+ Nígbà tó pa dà sọ́dọ̀ wọn, tó sì tún bá wọn sọ̀rọ̀, ó mú Síméónì+ láàárín wọn, ó sì dè é níṣojú+ wọn.
24 Ló bá kúrò lọ́dọ̀ wọn, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sunkún.+ Nígbà tó pa dà sọ́dọ̀ wọn, tó sì tún bá wọn sọ̀rọ̀, ó mú Síméónì+ láàárín wọn, ó sì dè é níṣojú+ wọn.