Jẹ́nẹ́sísì 37:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó ṣẹlẹ̀ pé à ń di ìtí ọkà ní àárín oko, ni ìtí tèmi bá dìde, ó nàró, àwọn ìtí tiyín sì tò yí ìtí tèmi ká, wọ́n sì tẹrí ba fún un.”+ Jẹ́nẹ́sísì 37:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lẹ́yìn ìyẹn, ó tún lá àlá míì, ó sì rọ́ ọ fún àwọn arákùnrin rẹ̀, ó ní: “Mo tún lá àlá míì. Lọ́tẹ̀ yìí, oòrùn àti òṣùpá àti ìràwọ̀ mọ́kànlá (11) ń tẹrí ba fún mi.”+ Jẹ́nẹ́sísì 42:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jósẹ́fù ló ní àṣẹ lórí ilẹ̀+ Íjíbítì, òun ló sì ń ta ọkà fún gbogbo èèyàn tó wà láyé.+ Àwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù dé, wọ́n tẹrí ba fún un, wọ́n sì wólẹ̀.+
7 Ó ṣẹlẹ̀ pé à ń di ìtí ọkà ní àárín oko, ni ìtí tèmi bá dìde, ó nàró, àwọn ìtí tiyín sì tò yí ìtí tèmi ká, wọ́n sì tẹrí ba fún un.”+
9 Lẹ́yìn ìyẹn, ó tún lá àlá míì, ó sì rọ́ ọ fún àwọn arákùnrin rẹ̀, ó ní: “Mo tún lá àlá míì. Lọ́tẹ̀ yìí, oòrùn àti òṣùpá àti ìràwọ̀ mọ́kànlá (11) ń tẹrí ba fún mi.”+
6 Jósẹ́fù ló ní àṣẹ lórí ilẹ̀+ Íjíbítì, òun ló sì ń ta ọkà fún gbogbo èèyàn tó wà láyé.+ Àwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù dé, wọ́n tẹrí ba fún un, wọ́n sì wólẹ̀.+