Jẹ́nẹ́sísì 42:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jósẹ́fù ló ní àṣẹ lórí ilẹ̀+ Íjíbítì, òun ló sì ń ta ọkà fún gbogbo èèyàn tó wà láyé.+ Àwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù dé, wọ́n tẹrí ba fún un, wọ́n sì wólẹ̀.+ Jẹ́nẹ́sísì 42:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Jósẹ́fù rántí àwọn àlá tó lá nípa wọn, ó sì sọ fún wọn+ pé: “Amí ni yín! Ṣe lẹ wá wo ibi tí ẹ ti lè gbógun ja ilẹ̀ wa!”*
6 Jósẹ́fù ló ní àṣẹ lórí ilẹ̀+ Íjíbítì, òun ló sì ń ta ọkà fún gbogbo èèyàn tó wà láyé.+ Àwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù dé, wọ́n tẹrí ba fún un, wọ́n sì wólẹ̀.+
9 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Jósẹ́fù rántí àwọn àlá tó lá nípa wọn, ó sì sọ fún wọn+ pé: “Amí ni yín! Ṣe lẹ wá wo ibi tí ẹ ti lè gbógun ja ilẹ̀ wa!”*