ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 37:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Wọ́n rí Jósẹ́fù tó ń bọ̀ ní ọ̀ọ́kán, àmọ́ kó tó dé ọ̀dọ̀ wọn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í gbìmọ̀ pọ̀ kí wọ́n lè pa á.

  • Jẹ́nẹ́sísì 37:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Nígbà tí àwọn oníṣòwò tí wọ́n jẹ́ ọmọ Mídíánì+ ń kọjá lọ, wọ́n fa Jósẹ́fù jáde látinú kòtò omi náà, wọ́n sì tà á fún àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì ní ogún (20) ẹyọ fàdákà.+ Ni àwọn ọkùnrin yìí bá mú Jósẹ́fù lọ sí Íjíbítì.

  • Jẹ́nẹ́sísì 42:21, 22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Wọ́n sọ fún ara wọn pé: “Ó dájú pé torí Jósẹ́fù+ ni ìyà yìí ṣe ń jẹ wá, torí a rí ìdààmú tó bá a* nígbà tó bẹ̀ wá pé ká yọ́nú sí òun, àmọ́ a ò dá a lóhùn. Ìdí nìyẹn tí wàhálà yìí fi dé bá wa.” 22 Ni Rúbẹ́nì bá sọ fún wọn pé: “Ṣebí mo sọ fún yín pé, ‘Ẹ má ṣẹ ọmọ náà,’ àmọ́ ṣé ẹ dá mi lóhùn?+ Ẹ̀san+ ti wá dé báyìí torí ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́