Jẹ́nẹ́sísì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó sọ fún Ádámù* pé: “Torí o fetí sí ìyàwó rẹ, tí o sì jẹ èso igi tí mo pàṣẹ+ fún ọ pé, ‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ,’ ègún ni fún ilẹ̀ nítorí rẹ.+ Inú ìrora ni wàá ti máa jẹ èso rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.+
17 Ó sọ fún Ádámù* pé: “Torí o fetí sí ìyàwó rẹ, tí o sì jẹ èso igi tí mo pàṣẹ+ fún ọ pé, ‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ,’ ègún ni fún ilẹ̀ nítorí rẹ.+ Inú ìrora ni wàá ti máa jẹ èso rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.+