-
Jẹ́nẹ́sísì 47:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ilẹ̀ Íjíbítì wà ní ìkáwọ́ rẹ. Jẹ́ kí bàbá rẹ àti àwọn arákùnrin rẹ máa gbé ibi tó dáa jù ní ilẹ̀+ yìí. Kí wọ́n máa gbé nílẹ̀ Góṣénì. Tí o bá sì mọ àwọn tó dáńgájíá nínú wọn, jẹ́ kí wọ́n máa bójú tó ẹran ọ̀sìn mi.”
-