-
Jẹ́nẹ́sísì 42:21, 22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Wọ́n sọ fún ara wọn pé: “Ó dájú pé torí Jósẹ́fù+ ni ìyà yìí ṣe ń jẹ wá, torí a rí ìdààmú tó bá a* nígbà tó bẹ̀ wá pé ká yọ́nú sí òun, àmọ́ a ò dá a lóhùn. Ìdí nìyẹn tí wàhálà yìí fi dé bá wa.” 22 Ni Rúbẹ́nì bá sọ fún wọn pé: “Ṣebí mo sọ fún yín pé, ‘Ẹ má ṣẹ ọmọ náà,’ àmọ́ ṣé ẹ dá mi lóhùn?+ Ẹ̀san+ ti wá dé báyìí torí ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.”
-