ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 10:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ṣémù náà bímọ, òun ni baba ńlá gbogbo àwọn ọmọ Ébérì,+ òun sì ni arákùnrin Jáfẹ́tì tó jẹ́ ẹ̀gbọ́n pátápátá.*

  • Jẹ́nẹ́sísì 11:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ìtàn Ṣémù+ nìyí.

      Ẹni ọgọ́rùn-ún (100) ọdún ni Ṣémù nígbà tó bí Ápákíṣádì+ ní ọdún kejì lẹ́yìn Ìkún Omi.

  • Lúùkù 3:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọ

      Jósẹ́fù,+

      ọmọ Hélì,

  • Lúùkù 3:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 ọmọ Káínánì,

      ọmọ Ápákíṣádì,+

      ọmọ Ṣémù,+

      ọmọ Nóà,+

      ọmọ Lámékì,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́