Nọ́ńbà 26:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Rúbẹ́nì,+ àkọ́bí Ísírẹ́lì; àwọn ọmọ+ Rúbẹ́nì nìyí: látọ̀dọ̀ Hánókù, ìdílé àwọn ọmọ Hánókù; látọ̀dọ̀ Pálù, ìdílé àwọn ọmọ Pálù; 6 látọ̀dọ̀ Hésírónì, ìdílé àwọn ọmọ Hésírónì; látọ̀dọ̀ Kámì, ìdílé àwọn ọmọ Kámì.
5 Rúbẹ́nì,+ àkọ́bí Ísírẹ́lì; àwọn ọmọ+ Rúbẹ́nì nìyí: látọ̀dọ̀ Hánókù, ìdílé àwọn ọmọ Hánókù; látọ̀dọ̀ Pálù, ìdílé àwọn ọmọ Pálù; 6 látọ̀dọ̀ Hésírónì, ìdílé àwọn ọmọ Hésírónì; látọ̀dọ̀ Kámì, ìdílé àwọn ọmọ Kámì.