Jẹ́nẹ́sísì 46:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì tó wá sí Íjíbítì + nìyí, Jékọ́bù àti àwọn ọmọ rẹ̀: Rúbẹ́nì+ ni àkọ́bí Jékọ́bù. 9 Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì ni Hánókù, Pálù, Hésírónì àti Kámì.+ Ẹ́kísódù 6:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn olórí agbo ilé àwọn bàbá wọn nìyí: Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, àkọ́bí Ísírẹ́lì+ ni Hánókù, Pálù, Hésírónì àti Kámì.+ Àwọn ni ìdílé Rúbẹ́nì.
8 Orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì tó wá sí Íjíbítì + nìyí, Jékọ́bù àti àwọn ọmọ rẹ̀: Rúbẹ́nì+ ni àkọ́bí Jékọ́bù. 9 Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì ni Hánókù, Pálù, Hésírónì àti Kámì.+
14 Àwọn olórí agbo ilé àwọn bàbá wọn nìyí: Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, àkọ́bí Ísírẹ́lì+ ni Hánókù, Pálù, Hésírónì àti Kámì.+ Àwọn ni ìdílé Rúbẹ́nì.