Jẹ́nẹ́sísì 30:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Jósẹ́fù,*+ ó sì sọ pé: “Jèhófà ti fún mi ní ọmọkùnrin míì.”