-
Jẹ́nẹ́sísì 35:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Àwọn ọmọkùnrin tí Réṣẹ́lì bí ni Jósẹ́fù àti Bẹ́ńjámínì.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 45:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Jósẹ́fù sọ fún àwọn arákùnrin rẹ̀ pé: “Ẹ jọ̀ọ́, ẹ sún mọ́ mi.” Ni wọ́n bá sún mọ́ ọn.
Ó sọ pé: “Èmi ni Jósẹ́fù arákùnrin yín, tí ẹ tà sí Íjíbítì.+
-
-
Diutarónómì 33:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ó sọ nípa Jósẹ́fù pé:+
-