Jẹ́nẹ́sísì 30:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Réṣẹ́lì wá sọ pé: “Ìjàkadì gidi ni mo bá ẹ̀gbọ́n mi jà. Mo sì ti borí!” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Náfútálì.*+
8 Réṣẹ́lì wá sọ pé: “Ìjàkadì gidi ni mo bá ẹ̀gbọ́n mi jà. Mo sì ti borí!” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Náfútálì.*+