-
Jẹ́nẹ́sísì 35:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Àwọn ọmọkùnrin tí Bílíhà ìránṣẹ́ Réṣẹ́lì bí ni Dánì àti Náfútálì.
-
-
Diutarónómì 33:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ó sọ nípa Náfútálì pé:+
“Jèhófà ti tẹ́wọ́ gba Náfútálì
Ó sì ti bù kún un lọ́pọ̀lọpọ̀.
Gba ìwọ̀ oòrùn àti gúúsù.”
-