Jẹ́nẹ́sísì 43:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Wọ́n gbé oúnjẹ tirẹ̀ fún un lọ́tọ̀, tiwọn náà wà lọ́tọ̀, àwọn ará Íjíbítì tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀ sì jẹun lọ́tọ̀, torí àwọn ará Íjíbítì kò lè bá àwọn Hébérù jẹun, torí pé ohun ìríra ló jẹ́ lójú àwọn ará Íjíbítì.+
32 Wọ́n gbé oúnjẹ tirẹ̀ fún un lọ́tọ̀, tiwọn náà wà lọ́tọ̀, àwọn ará Íjíbítì tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀ sì jẹun lọ́tọ̀, torí àwọn ará Íjíbítì kò lè bá àwọn Hébérù jẹun, torí pé ohun ìríra ló jẹ́ lójú àwọn ará Íjíbítì.+