Jẹ́nẹ́sísì 8:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Jèhófà sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbọ́ òórùn dídùn.* Jèhófà wá sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: “Mi ò tún ní fi ilẹ̀+ gégùn-ún* mọ́ torí èèyàn, torí pé kìkì ibi ni èèyàn ń rò lọ́kàn láti ìgbà èwe rẹ̀ wá;+ mi ò sì tún ní pa gbogbo ohun alààyè run mọ́, bí mo ti ṣe.+ Jeremáyà 17:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ọkàn ń tanni jẹ* ju ohunkóhun lọ, kò sóhun tí kò lè ṣe.*+ Ta ló lè mọ̀ ọ́n? Mátíù 15:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bí àpẹẹrẹ, inú ọkàn ni àwọn èrò burúkú ti ń wá,+ irú bí: ìpànìyàn, àgbèrè, ìṣekúṣe,* olè jíjà, ìjẹ́rìí èké, ọ̀rọ̀ òdì.
21 Jèhófà sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbọ́ òórùn dídùn.* Jèhófà wá sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: “Mi ò tún ní fi ilẹ̀+ gégùn-ún* mọ́ torí èèyàn, torí pé kìkì ibi ni èèyàn ń rò lọ́kàn láti ìgbà èwe rẹ̀ wá;+ mi ò sì tún ní pa gbogbo ohun alààyè run mọ́, bí mo ti ṣe.+
19 Bí àpẹẹrẹ, inú ọkàn ni àwọn èrò burúkú ti ń wá,+ irú bí: ìpànìyàn, àgbèrè, ìṣekúṣe,* olè jíjà, ìjẹ́rìí èké, ọ̀rọ̀ òdì.