Jẹ́nẹ́sísì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó sọ fún Ádámù* pé: “Torí o fetí sí ìyàwó rẹ, tí o sì jẹ èso igi tí mo pàṣẹ+ fún ọ pé, ‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ,’ ègún ni fún ilẹ̀ nítorí rẹ.+ Inú ìrora ni wàá ti máa jẹ èso rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.+ Jẹ́nẹ́sísì 5:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Nóà,*+ ó sọ pé: “Ọmọ yìí á tù wá nínú* nídìí iṣẹ́ wa àti làálàá tí a ṣe torí ilẹ̀ tí Jèhófà ti fi gégùn-ún.”+
17 Ó sọ fún Ádámù* pé: “Torí o fetí sí ìyàwó rẹ, tí o sì jẹ èso igi tí mo pàṣẹ+ fún ọ pé, ‘O ò gbọ́dọ̀ jẹ,’ ègún ni fún ilẹ̀ nítorí rẹ.+ Inú ìrora ni wàá ti máa jẹ èso rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.+
29 Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Nóà,*+ ó sọ pé: “Ọmọ yìí á tù wá nínú* nídìí iṣẹ́ wa àti làálàá tí a ṣe torí ilẹ̀ tí Jèhófà ti fi gégùn-ún.”+