Jẹ́nẹ́sísì 41:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Jósẹ́fù+ ti bí ọmọkùnrin méjì kí ìyàn tó bẹ̀rẹ̀ sí í mú. Ásénátì ọmọ Pọ́tíférà àlùfáà Ónì* ló bí àwọn ọmọ náà fún un. Jóṣúà 14:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀yà méjì ni wọ́n ka àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù sí,+ ìyẹn Mánásè àti Éfúrémù;+ wọn ò pín lára ilẹ̀ náà fún àwọn ọmọ Léfì, àfi àwọn ìlú+ tí wọ́n á máa gbé àti ibi tí àwọn ẹran ọ̀sìn wọn á ti máa jẹko, tí ohun ìní wọn sì máa wà.+
50 Jósẹ́fù+ ti bí ọmọkùnrin méjì kí ìyàn tó bẹ̀rẹ̀ sí í mú. Ásénátì ọmọ Pọ́tíférà àlùfáà Ónì* ló bí àwọn ọmọ náà fún un.
4 Ẹ̀yà méjì ni wọ́n ka àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù sí,+ ìyẹn Mánásè àti Éfúrémù;+ wọn ò pín lára ilẹ̀ náà fún àwọn ọmọ Léfì, àfi àwọn ìlú+ tí wọ́n á máa gbé àti ibi tí àwọn ẹran ọ̀sìn wọn á ti máa jẹko, tí ohun ìní wọn sì máa wà.+