Jẹ́nẹ́sísì 48:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tèmi+ ni àwọn ọmọ rẹ méjèèjì tí o bí ní ilẹ̀ Íjíbítì kí n tó wá sọ́dọ̀ rẹ ní Íjíbítì. Éfúrémù àti Mánásè yóò di tèmi bí Rúbẹ́nì àti Síméónì ṣe jẹ́ tèmi.+ 1 Kíróníkà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Òótọ́ ni pé Júdà+ ta yọ àwọn arákùnrin rẹ̀, ọ̀dọ̀ rẹ̀ sì ni ẹni tó máa jẹ́ aṣáájú+ ti wá, síbẹ̀ Jósẹ́fù ló ni ẹ̀tọ́ àkọ́bí.
5 Tèmi+ ni àwọn ọmọ rẹ méjèèjì tí o bí ní ilẹ̀ Íjíbítì kí n tó wá sọ́dọ̀ rẹ ní Íjíbítì. Éfúrémù àti Mánásè yóò di tèmi bí Rúbẹ́nì àti Síméónì ṣe jẹ́ tèmi.+
2 Òótọ́ ni pé Júdà+ ta yọ àwọn arákùnrin rẹ̀, ọ̀dọ̀ rẹ̀ sì ni ẹni tó máa jẹ́ aṣáájú+ ti wá, síbẹ̀ Jósẹ́fù ló ni ẹ̀tọ́ àkọ́bí.