Jẹ́nẹ́sísì 41:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Jósẹ́fù sọ àkọ́bí rẹ̀ ní Mánásè,*+ torí ó sọ pé, “Ọlọ́run ti mú kí n gbàgbé gbogbo ìdààmú tó bá mi àti gbogbo ilé bàbá mi.” Jẹ́nẹ́sísì 46:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ásénátì+ ọmọ Pọ́tíférà àlùfáà Ónì* bí Mánásè+ àti Éfúrémù+ fún Jósẹ́fù ní ilẹ̀ Íjíbítì.
51 Jósẹ́fù sọ àkọ́bí rẹ̀ ní Mánásè,*+ torí ó sọ pé, “Ọlọ́run ti mú kí n gbàgbé gbogbo ìdààmú tó bá mi àti gbogbo ilé bàbá mi.”