Jẹ́nẹ́sísì 5:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Lẹ́yìn tí Nóà pé ẹni ọgọ́rùn-ún márùn-ún (500) ọdún, ó bí Ṣémù,+ Hámù+ àti Jáfẹ́tì.+