Jẹ́nẹ́sísì 34:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Àmọ́ ní ọjọ́ kẹta, nígbà tí wọ́n ṣì ń jẹ̀rora, àwọn ọmọ Jékọ́bù méjì, Síméónì àti Léfì tí wọ́n jẹ́ ẹ̀gbọ́n+ Dínà mú idà wọn, wọ́n yọ́ lọ sí ìlú náà, wọ́n sì pa gbogbo ọkùnrin.+
25 Àmọ́ ní ọjọ́ kẹta, nígbà tí wọ́n ṣì ń jẹ̀rora, àwọn ọmọ Jékọ́bù méjì, Síméónì àti Léfì tí wọ́n jẹ́ ẹ̀gbọ́n+ Dínà mú idà wọn, wọ́n yọ́ lọ sí ìlú náà, wọ́n sì pa gbogbo ọkùnrin.+