-
Hébérù 7:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Torí ó ṣe kedere pé ọ̀dọ̀ Júdà ni Olúwa wa ti ṣẹ̀ wá,+ síbẹ̀, Mósè ò sọ pé àlùfáà kankan máa wá látinú ẹ̀yà yẹn.