-
1 Kíróníkà 7:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àwọn arákùnrin wọn tó wà ní gbogbo ìdílé Ísákà jẹ́ jagunjagun tó lákíkanjú. Gbogbo wọn jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́tàdínláàádọ́rùn-ún (87,000), bí orúkọ wọn ṣe wà nínú àkọsílẹ̀ ìdílé wọn.+
-